Tuesday 20 September 2016

Ìsosíwájú àtẹ̀yínwá

Mo gbésẹ̀ láì jẹ gbèsè,
Mo dájú láì jẹ̣́́ ọ̀dájú,
Mi ò díbọ́ láti dìbò,
Ọ̀rọ̀ kún ó sọ mí dodi.
Ìbáe ní abáj,
Ì̀wádìí ni olórí ìmọ̀,
Àìbíkítà àti àìka ìnkan kún,
Ló da ẹgbẹ́ májè́óbàjé rú.
Fàmílétí kí mo gbọ,
Fi ìganrán lé tìróò,
Ọmọ amúnisúre,
Má fijà tẹ́ mi.
Ẹni ò mọ̀ wẹ̀ ò mòwe,
Ati jáwọ́ nínú àgàbàgebè,
Àti rí fúró adìyẹ,
Ì
e àná ti di ìekúe òní.
Gbérè omo,
Bẹ́ẹ̀ni kí o máae,
Mámà yíwà padà,
K
óníkálùkù farapamọ́.

No comments:

Post a Comment

Comments are accepted if in context are polite and hopefully without expletives and should show a name, anonymous, would not do. Thanks.